ログイン  | 新規登録
歌詞投稿コミュニティ「プチリリ」

TOP > 歌詞 > Eniyan Bi Aparo
Eniyan Bi Aparo

アーティスト:Tunji Oyelana 

  • お気に入り登録




Verse 1: Mo lo soko Mo boluoko Oni nwa gba Isu Oro isu ko londun mi Mo lo sodo Mo boluweri Oni nwa gba-eja Oro eja ko londun mi Mo de inugbo Mo boluode soro Oni nwa gbetu Oro etu ko londun mi Mo de buka Awon ore mi nbuta Won ni nwa pokele Oro ebi ko lonse me Mo ni ya bete Igba nla nii ti mi Won ni nwa mu oguro Oro emu ko lonse mi Mo wa dele Mo ba Ronke mi soro o Oni nwa wora Oro ara ko lonse mi Olufe ni baga Kilo de todorikodo Ni mba ko Ni mba ro Oro gbogbo aiye londun mi Verse 2: Bo ba o pa o Lomo araye o Bi oba o bu lese Lomo araye o Bo ba ni lowo Ka ba eje o Lomo araye o Bo si ni mo Ka ba ese soro Lomo araye o Bo ni iwa to da Ka ba e je o Lomo araye o Bi iwa re osi da Ka yera fun e o Lomo araye o Bo ni ise to da Ka gba mo e lowo Lomo araye o Bi o si rise Ka fi e se yeye o Lomo araye o Bo niyawo to da Ka ba e fe Lomo araye o Biyawo e o si da


投稿者: PetitLyrics
プチリリ再生回数:0





日本語English

利用規約プライバシーポリシー許諾情報運営会社お問い合わせヘルプ
© 2024 SyncPower Corporation


Page
Top